Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe ore fun iranṣẹ rẹ, nitoripe iwọ ti mu iranṣẹ rẹ wọ inu majẹmu Oluwa pẹlu rẹ; ṣugbọn bi ìwa buburu ba mbẹ li ọwọ mi, iwọ tikararẹ pa mi; ẽṣe ti iwọ o fi mu mi tọ baba rẹ lọ?

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:8 ni o tọ