Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ọmọdekunrin na ti lọ tan, Dafidi si dide lati iha gusu, o si wolẹ, o si tẹriba lẹrinmẹta: nwọn si fi ẹnu ko ara wọn li ẹnu, nwọn si jumọ sọkun, ekini keji wọn, titi Dafidi fi bori.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:41 ni o tọ