Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Jonatani sì fi ibinu dide kuro ni ibi onjẹ, kò si jẹn ní ijọ keji oṣu na: inu rẹ̀ si bajẹ gidigidi fun Dafidi, nitoripe baba rẹ̀ doju tì i.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:34 ni o tọ