Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Jọwọ, jẹ ki emi ki o lọ; nitoripe idile wa li ẹbọ kan iru ni ilu na; ẹgbọn mi si paṣẹ fun mi pe ki emi ki o má ṣaiwà nibẹ; njẹ, bi emi ba ri oju rere gbà lọdọ rẹ, jọwọ, jẹ ki emi lọ, ki emi ri awọn ẹgbọn mi. Nitorina ni ko ṣe wá si ibi onjẹ ọba.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:29 ni o tọ