Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, ni ijọ keji, ti o jẹ ijọ keji oṣu, ipò Dafidi si ṣofo; Saulu si wi fun Jonatani ọmọ rẹ̀ pe, Ẽṣe ti ọmọ Jesse ko fi wá si ibi onjẹ lana ati loni?

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:27 ni o tọ