Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi emi ba wi bayi fun ọmọde-kọnrin na pe, Wõ ọfa na mbẹ niwaju rẹ; njẹ ma ba tirẹ lọ; Oluwa li o rán ọ lọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:22 ni o tọ