Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 20:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Oluwa ki o ṣe bẹ̃ ati ju bẹ̃ lọ si Jonatani: ṣugbọn bi o ba si ṣe pe o wu baba mi lati ṣe buburu si ọ, emi o si sọ ọ li eti rẹ, emi o si jẹ ki o lọ, iwọ o si lọ li alafia, ki Oluwa ki o si pẹlu rẹ gẹgẹ bi o ti wà pẹlu baba mi.

Ka pipe ipin 1. Sam 20

Wo 1. Sam 20:13 ni o tọ