Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 2:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, olukuluku ẹniti o ba kù ni ile rẹ yio wá tẹriba fun u nitori fadaka diẹ, ati nitori okele onjẹ, yio si wipe, Jọwọ fi mi sinu ọkan ninu iṣẹ awọn alufa, ki emi ki o le ma ri akara diẹ jẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:36 ni o tọ