Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 2:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eṣe ti ẹnyin fi tapa si ẹbọ ati ọrẹ mi, ti mo pa li aṣẹ ni ibujoko mi: iwọ si bu ọla fun awọn ọmọ rẹ jù mi lọ, ti ẹ si fi gbogbo ãyo ẹbọ Israeli awọn enia mi mu ara nyin sanra?

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:29 ni o tọ