Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin na si wi fun u pe, Jẹ ki wọn sun ọra na nisisiyi, ki o si mu iyekiye ti ọkàn rẹ ba fẹ; nigbana li o da a lohun pe, Bẹ̃kọ, ṣugbọn ki iwọ ki o fi i fun mi nisisiyi: bikoṣe bẹ̃, emi o fi agbara gbà a.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:16 ni o tọ