Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

On a si fi gun inu apẹ, tabi kẹtili tabi òdu, tabi ikokò, gbogbo eyi ti ọpa-ẹran oniga na ba mu wá oke, alufa a mu u fun ara rẹ̀. Bẹ̃ni nwọn nṣe si gbogbo Israeli ti o wá si ibẹ̀ ni Ṣilo.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:14 ni o tọ