Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 2:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

HANNA si gbadura pe, Ọkàn mi yọ̀ si Oluwa, iwo mi li a si gbe soke si Oluwa: ẹnu mi si gboro lori awọn ọta mi; nitoriti emi yọ̀ ni igbala rẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 2

Wo 1. Sam 2:1 ni o tọ