Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 19:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jonatani si sọ̀rọ Dafidi ni rere fun Saulu baba rẹ̀, o si wi fun u pe, Ki a máṣe jẹ ki ọba ki o ṣẹ̀ si iranṣẹ rẹ̀, si Dafidi; nitori kò ṣẹ̀ ọ, ati nitoripe iṣẹ rẹ̀ dara gidigidi fun ọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 19

Wo 1. Sam 19:4 ni o tọ