Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 19:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

On na si lọ si Rama, o si de ibi kanga nla kan ti o wà ni Seku: o si bere, o si wipe, Nibo ni Samueli ati Dafidi gbe wà? ẹnikan si wipe, Wõ, nwọn mbẹ ni Naoti ni Rama.

Ka pipe ipin 1. Sam 19

Wo 1. Sam 19:22 ni o tọ