Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ijọ keji, ti ẹmi buburu lati ọdọ Ọlọrun wá si ba le Saulu, on si sọtẹlẹ li arin ile; Dafidi si fi ọwọ́ rẹ̀ ṣire lara duru bi igba atẹhinwa; ẹṣín kan mbẹ lọwọ Saulu.

Ka pipe ipin 1. Sam 18

Wo 1. Sam 18:10 ni o tọ