Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si duro o si kigbe si ogun Israeli, o si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin jade lati tẹgun? ṣe Filistini kan li emi iṣe? ẹnyin si jẹ ẹrú Saulu. Ẹnyin yan ọkunrin kan fun ara nyin, ki ẹnyin si jẹ ki o sọkale tọ̀ mi wá.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:8 ni o tọ