Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si sure, o si duro lori Filistini na, o si mu ida rẹ̀, o si fà a yọ ninu akọ̀ rẹ̀, o si pa a, o si fi idà na bẹ́ ẹ li ori. Nigbati awọn Filistini si ri pe akikanju wọn kú, nwọn si sa.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:51 ni o tọ