Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun Filistini na pe, Iwọ mu idà, ati ọ̀kọ, ati awà tọ̀ mi wá; ṣugbọn emi tọ̀ ọ wá li orukọ Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun ogun Israeli ti iwọ ti gàn.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:45 ni o tọ