Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliabu ẹgbọn rẹ̀ si gbọ́ nigbati on ba awọn ọkunrin na sọ̀rọ; Eliabu si binu si Dafidi, o si wipe, Ẽ ti ṣe ti iwọ fi sọkalẹ wá ihinyi, tani iwọ ha fi agutan diẹ nì le lọwọ́ li aginju? emi mọ̀ igberaga rẹ, ati buburu ọkàn rẹ; nitori lati ri ogun ni iwọ ṣe sọkalẹ wá.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:28 ni o tọ