Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Israeli si wipe, Ẹnyin kò ri ọkunrin yi ti o goke wá ihin? lati pe Israeli ni ijà li o ṣe wá: yio si ṣe pe, ẹniti o ba pa ọkunrin na, ọba yio si fi ọrọ̀ pipọ fun u, yio si fun u li ọmọ rẹ̀ obinrin, yio si sọ ile baba rẹ di omnira ni Israeli.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:25 ni o tọ