Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi on si ti mba wọn sọ̀rọ, sa wõ, akikanju ọkunrin na, Filistini ti Gati, ti orukọ rẹ̀ njẹ Goliati si goke wá, lati ogun awọn Filistini, o si sọ gẹgẹ bi ọ̀rọ ti o ti nsọ ri: Dafidi si gbọ́.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:23 ni o tọ