Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN Filistini si gbá ogun wọn jọ si oju ijà, nwọn si gba ara wọn jọ si Ṣoko, ti iṣe ti Juda, nwọn si do si Ṣoko ati Aseka, ni Efesdammimi.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:1 ni o tọ