Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 15:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Saulu ati awọn enia na da Agagi si, ati eyi ti o dara julọ ninu agutan ati ninu malu, ati ohun eyi ti o dara tobẹ̃ ninu wọn, ati ọdọ-agutan abọpa, ati gbogbo nkan ti o dara; nwọn kò si fẹ pa wọn run: ṣugbọn gbogbo nkan ti kò dara ti kò si nilari ni nwọn parun patapata.

Ka pipe ipin 1. Sam 15

Wo 1. Sam 15:9 ni o tọ