Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si jọba lori Israeli; o si bá gbogbo awọn ọta rẹ̀ jà yika, eyini ni Moabu ati awọn ọmọ Ammoni, ati Edomu, ati awọn ọba Soba ati awọn Filistini: ati ibikibi ti o yi si, a bà wọn ninu jẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:47 ni o tọ