Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia si wi fun Saulu pe, Jonatani yio kú, ti o ṣe igbala nla yi ni Israeli? ki a má ri i; bi Oluwa ti wà, ọkan ninu irun ori rẹ̀ kì yio bọ́ silẹ; nitoripe o ba Ọlọrun ṣiṣẹ pọ̀ loni. Bẹ̃li awọn enia si gbà Jonatani silẹ, kò si kú.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:45 ni o tọ