Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn enia si wọ inu igbo na, si kiye si i oyin na nkán; ṣugbọn kò si ẹnikan ti o mu ọwọ́ rẹ̀ re ẹnu rẹ̀: nitoripe awọn enia bẹ̀ru ifibu na.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:26 ni o tọ