Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu awọn Heberu ti o wà lọdọ awọn Filistini nigba atijọ, ti o si ti goke ba wọn lọ si budo lati ilu ti o wà yikakiri, awọn na pẹlu si yipada lati dapọ̀ mọ awọn Israeli ti o wà lọdọ Saulu ati Jonatani.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:21 ni o tọ