Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi Saulu ti mba alufa na sọ̀rọ, ariwo ti o wà ni budo awọn Filistini si npọ̀ si i: Saulu si wi fun alufa na pe, dawọ́ duro.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:19 ni o tọ