Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 14:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si wi fun awọn enia ti o wà lọdọ rẹ̀ pe, Njẹ ẹ kà awọn enia na ki ẹ si mọ̀ ẹniti o jade kuro ninu wa. Nwọn si kà, si kiye si i, Jonatani ati ẹniti o rù ihamọra rẹ̀ kò si si.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:17 ni o tọ