Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si bi i pe, Kini iwọ ṣe yi? Saulu si dahùn pe, Nitoriti emi ri pe awọn enia na ntuka kuro lọdọ mi, iwọ kò si wá li akoko ọjọ ti o dá, awọn Filistini si ko ara wọn jọ ni Mikmaṣi.

Ka pipe ipin 1. Sam 13

Wo 1. Sam 13:11 ni o tọ