Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 12:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Oluwa li ẹlẹri si nyin, ati ẹni ami-ororo rẹ̀ ni ẹlẹri loni pe, ẹnyin kò rí nkan lọwọ́ mi. Nwọn si dahùn wipe, On li ẹlẹri.

Ka pipe ipin 1. Sam 12

Wo 1. Sam 12:5 ni o tọ