Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 12:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oni ki ọjọ ikore ọka bi? emi o kepe Oluwa, yio si ran ãra ati ojò; ẹnyin o si mọ̀, ẹnyin o si ri pe iwabuburu nyin pọ̀, ti ẹnyin ṣe li oju Oluwa ni bibere ọba fun ara nyin.

Ka pipe ipin 1. Sam 12

Wo 1. Sam 12:17 ni o tọ