Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin eyini iwọ o wá si oke Ọlọrun, nibiti ẹgbẹ ogun awọn Filistini wà; yio si ṣe, nigbati iwọ ba de ilu na, iwọ o si pade ẹgbẹ woli ti yio ma sọkalẹ lati ibi giga nì wá; nwọn o si ni psalteri, ati tabreti, ati fère, ati harpu niwaju wọn, nwọn o si ma sọtẹlẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 10

Wo 1. Sam 10:5 ni o tọ