Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 10:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si kọja lati ibẹ lọ, iwọ o si de pẹtẹlẹ Tabori, nibẹ li ọkunrin mẹta ti nlọ sọdọ Ọlọrun ni Beteli yio pade rẹ, ọkan yio mu, ọmọ ewurẹ mẹta lọwọ, ekeji yio mu iṣù akara mẹta, ati ẹkẹta yio mu igo ọti-waini.

Ka pipe ipin 1. Sam 10

Wo 1. Sam 10:3 ni o tọ