Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 1:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ Hanna, on nsọ̀rọ li ọkàn rẹ̀; kiki etè rẹ̀ li o nmì, ṣugbọn a kò gbọ́ ohùn rẹ̀: nitorina ni Eli fi rò pe, o mu ọti-waini yó.

Ka pipe ipin 1. Sam 1

Wo 1. Sam 1:13 ni o tọ