Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 7:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati leti ilu awọn ọmọ Manasse, Betṣeani, ati ilu rẹ̀, Taanaki ati ilu rẹ̀, Megiddo ati ilu rẹ̀, Dori ati ilu rẹ̀. Ninu awọn wọnyi li awọn ọmọ Josefu, ọmọ Israeli, ngbe.

Ka pipe ipin 1. Kro 7

Wo 1. Kro 7:29 ni o tọ