Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 6:15-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

15. Jehosadaki si lọ si oko ẹrú, nigbati Oluwa kó Juda ati Jerusalemu lọ nipa ọwọ Nebukadnessari.

16. Awọn ọmọ Lefi; Gersọmu, Kohati, ati Merari.

17. Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Gerṣomu, Libni, ati Ṣimei.

18. Awọn ọmọ Kohati ni, Amramu, ati Ishari, ati Hebroni, ati Ussieli.

19. Awọn ọmọ Merari; Mahli ati Muṣi. Wọnyi si ni idile awọn ọmọ Lefi, gẹgẹ bi awọn baba wọn.

20. Ti Gerṣomu; Libni ọmọ rẹ̀, Jahati ọmọ rẹ̀, Simma ọmọ rẹ̀.

21. Joa ọmọ rẹ̀, Iddo ọmọ rẹ̀, Sera ọmọ rẹ̀, Jeaterai ọmọ rẹ̀.

22. Awọn ọmọ Kohati; Amminadabu ọmọ rẹ̀, Kora ọmọ rẹ̀, Assiri ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Kro 6