Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 6:11-19 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. Asariah si bi Amariah, Amariah si bi Ahitubu,

12. Ahitubu si bi Sadoki, Sadoki si bi Ṣallumu,

13. Ṣallumu si bi Hilkiah, Hilkiah si bi Asariah,

14. Asariah si bi Seraiah, Seraiah si bi Jehosadaki,

15. Jehosadaki si lọ si oko ẹrú, nigbati Oluwa kó Juda ati Jerusalemu lọ nipa ọwọ Nebukadnessari.

16. Awọn ọmọ Lefi; Gersọmu, Kohati, ati Merari.

17. Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Gerṣomu, Libni, ati Ṣimei.

18. Awọn ọmọ Kohati ni, Amramu, ati Ishari, ati Hebroni, ati Ussieli.

19. Awọn ọmọ Merari; Mahli ati Muṣi. Wọnyi si ni idile awọn ọmọ Lefi, gẹgẹ bi awọn baba wọn.

Ka pipe ipin 1. Kro 6