Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 6:1-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AWỌN ọmọ Lefi; Gerṣoni, Kohati, ati Merari.

2. Ati awọn Kohati; Amramu, Ishari, ati Hebroni, ati Ussieli.

3. Ati awọn Amramu; Aaroni, ati Mose, ati Miriamu. Awọn ọmọ Aaroni; Nadabu, ati Abihu, Eleasari, ati Itamari.

4. Eleasari bi Finehasi, Finehasi si bi Abiṣua,

5. Abiṣua si bi Bukki, Bukki si bi Ussi,

6. Ussi si bi Serahiah, Serahiah si bi Meraioti,

7. Meraioti bi Amariah, Amariah si bi Ahitubu.

8. Ahitubu si bi Sadoku, Sadoku si bi Ahimaasi,

9. Ahimaasi si bi Asariah, Asariah si bi Johanani,

10. Johanani si bi Asariah (on na li ẹniti nṣiṣẹ alufa ni tempili ti Solomoni kọ́ ni Jerusalemu;)

11. Asariah si bi Amariah, Amariah si bi Ahitubu,

12. Ahitubu si bi Sadoki, Sadoki si bi Ṣallumu,

13. Ṣallumu si bi Hilkiah, Hilkiah si bi Asariah,

14. Asariah si bi Seraiah, Seraiah si bi Jehosadaki,

15. Jehosadaki si lọ si oko ẹrú, nigbati Oluwa kó Juda ati Jerusalemu lọ nipa ọwọ Nebukadnessari.

16. Awọn ọmọ Lefi; Gersọmu, Kohati, ati Merari.

17. Wọnyi si li orukọ awọn ọmọ Gerṣomu, Libni, ati Ṣimei.

18. Awọn ọmọ Kohati ni, Amramu, ati Ishari, ati Hebroni, ati Ussieli.

19. Awọn ọmọ Merari; Mahli ati Muṣi. Wọnyi si ni idile awọn ọmọ Lefi, gẹgẹ bi awọn baba wọn.

20. Ti Gerṣomu; Libni ọmọ rẹ̀, Jahati ọmọ rẹ̀, Simma ọmọ rẹ̀.

21. Joa ọmọ rẹ̀, Iddo ọmọ rẹ̀, Sera ọmọ rẹ̀, Jeaterai ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Kro 6