Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 5:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi si li awọn olori ile awọn baba wọn, Eferi, ati Iṣi, ati Elieli, ati Asrieli, ati Jeremiah, ati Hodafiah, ati Jahdieli, awọn alagbara akọni ọkunrin, ọkunrin olokiki, ati olori ile awọn baba wọn.

Ka pipe ipin 1. Kro 5

Wo 1. Kro 5:24 ni o tọ