Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 5:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Rubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati àbọ ẹ̀ya Manasse, ninu awọn ọkunrin alagbara ti nwọn ngbé asà ati idà, ti nwọn si nfi ọrun tafà, ti nwọn si mòye ogun, jẹ ọkẹ meji enia o le ẹgbẹrinlelogún o di ogoji, ti o jade lọ si ogun na.

Ka pipe ipin 1. Kro 5

Wo 1. Kro 5:18 ni o tọ