Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 4:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jabesi si ké pè Ọlọrun Israeli, wipe, Iwọ iba jẹ bukún mi nitõtọ, ki o si sọ àgbegbe mi di nla, ki ọwọ rẹ ki o si wà pẹlu mi, ati ki iwọ ki o má si jẹ ki emi ri ibi, ki emi má si ri ibinujẹ! Ọlọrun si mu ohun ti o tọrọ ṣẹ.

Ka pipe ipin 1. Kro 4

Wo 1. Kro 4:10 ni o tọ