Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 3:4-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

4. Awọn mẹfa wọnyi li a bi fun u ni Hebroni; nibẹ li o si jọba li ọdun meje on oṣù mẹfa: ati ni Jerusalemu li o jọba li ọdun mẹtalelọgbọn.

5. Wọnyi li a si bi fun u ni Jerusalemu; Ṣimea, ati Ṣobabu, ati Natani, ati Solomoni, mẹrin, lati ọdọ Batṣua ọmọbinrin Ammieli:

6. Abhari pẹlu, ati Eliṣama, ati Elifeleti,

7. Ati Noga, ati Nefegi, ati Jafia,

8. Ati Eliṣama, ati Eliada, ati Elifeleti mẹsan.

9. Wọnyi ni gbogbo awọn ọmọ Dafidi, laika awọn ọmọ àle rẹ̀, ati Tamari arabinrin wọn.

Ka pipe ipin 1. Kro 3