Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 26:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn arakunrin rẹ̀, awọn akọni enia, jẹ ẹgbã o le ẽdẹgbẹrin: gbogbo wọn jẹ awọn olori baba ti Dafidi ọba fi ṣe olori lori awọn ọmọ Rubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati àbọ ẹ̀ya Manasse, fun gbogbo ọ̀ran ti Ọlọrun ati ti ọba.

Ka pipe ipin 1. Kro 26

Wo 1. Kro 26:32 ni o tọ