Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 26:22-24 Yorùbá Bibeli (YCE)

22. Awọn ọmọ Jehieli; Setamu, ati Joeli arakunrin rẹ̀, ti o wà lori iṣura ile Oluwa.

23. Ninu ọmọ Amramu, ati ọmọ Ishari, ara Hebroni, ati ọmọ Ussieli:

24. Ati Ṣebueli ọmọ Gerṣomu, ọmọ Mose, ni onitọju iṣura.

Ka pipe ipin 1. Kro 26