Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 24:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

A si ri awọn ọkunrin ti o nṣe olori ninu awọn ọmọ Eleasari jù ti inu awọn ọmọ Itamari lọ, bayi li a si pin wọn. Ninu awọn ọmọ Eleasari, ọkunrin mẹrindilogun li o nṣe olori ni ile baba wọn, ati mẹjọ ninu awọn ọmọ Itamari, gẹgẹ bi ile baba wọn.

Ka pipe ipin 1. Kro 24

Wo 1. Kro 24:4 ni o tọ