Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 22:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, ninu ipọnju mi, emi ti pèse fun ile Oluwa na, ọkẹ marun talenti wura, ati ẹgbẹrun ẹgbẹrun talenti fadakà; ati ti idẹ, ati ti irin, laini ìwọn; nitori ọ̀pọlọpọ ni: ati ìti-igi ati okuta ni mo ti pèse; iwọ si le wá kún u.

Ka pipe ipin 1. Kro 22

Wo 1. Kro 22:14 ni o tọ