Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 19:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ọmọ Ammoni ri pe nwọn ti ba ara wọn jẹ lọdọ Dafidi, Hanuni ati awọn ọmọ Ammoni ran ẹgbẹrun talenti fadakà lati bẹ̀wẹ kẹkẹ́ ati ẹlẹsin lati Siria ni Mesopotamia wá, ati lati Siria-Maaka wá, ati lati Soba wá.

Ka pipe ipin 1. Kro 19

Wo 1. Kro 19:6 ni o tọ