Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibikibi ti mo ti nrin larin gbogbo Israeli, emi ha sọ̀rọ kan fun ọkan ninu awọn onidajọ Israeli, ti emi ti paṣẹ fun lati ma bọ awọn enia mi, emi ha ti wipe, Ẽṣe ti ẹnyin kò fi kọ́ ile igi kedari fun mi bi?

Ka pipe ipin 1. Kro 17

Wo 1. Kro 17:6 ni o tọ