Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 17:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Orilẹ-ède kan wo li o wà li aiye ti o dabi enia rẹ, Israeli, ti Ọlọrun lọ irapada lati ṣe enia on tikararẹ, lati ṣe orukọ fun ara rẹ nipa ohun ti o tobi ti o si lẹ̀ru, ni lile awọn orilẹ-ède jade kuro niwaju awọn enia rẹ, ti iwọ ti rapada lati Egipti jade wá?

Ka pipe ipin 1. Kro 17

Wo 1. Kro 17:21 ni o tọ